![]() |
Adekunle Gold ft. Lojay & Shoday - Bobo mp3 |
A real deal with the biggest street vibe crooners 'Adekunle Gold, Lojay and Shoday'. Their collaboration team up to be a hit in "Bobo". Enjoy the sound and feel the vibes
Bọbọ bọbọ
Na easy sabalili bọbọ bọbọ
Olowo laye mọ ko foloṣi
Ọmọ mẹta lo n wa mi
Amaka, Joy and Bisi
Wọn ni pe mo nawo bi Saraki
Yatọ s'awọn BTC Wire
High market value mo d'Aswani
Born to be soft, forced to be tough
Coupe coupe bibamba
Baba lo n ṣọla I'm just a spender
When they say no way, way, way, way
Ṣebi Oluwa lo n ṣe ṣe ṣe ṣe
Price me uppie iweka ka
Wọn gba fẹlẹlẹ mo n gba kaka
Spinall put my songi pon replay
Confetti make the money spray
Daddy Showkey lo n jo Galala
AG Baby ẹja nla nla
See bọbọ bọbọ
Na easy sabalili bọbọ bọbọ
Olowo laye mọ ko foloṣi
Bọbọ bọbọ
Na easy sabalili bọbọ bọbọ
Olowo laye mọ ko foloṣi
Quotable lyrics
Download mp3 Now
No comments:
Post a Comment
Drop Your Comments